IKEDE PATAKI
Ijọba ipinle Eko n rọ araalu paapaa gbogbo olugbe Magodo Residential Scheme lati fọkanbalẹ lori iṣẹlẹ to waye laipẹ yii ti Oloye Adebayọ Adeyiga atawọn ẹgbẹ Shangisha Landlords Association fi ẹtan ko awọn ọlọpaa lọ si Magodo lati fi tipa fidi idajọ ile-ẹjọ mulẹ. Ijọba ṣakiyesi pe awọn ọlọpaa ti wọn waa fidi idajọ naa […]